Forum

Notifications
Clear all

Owe Yoruba - Yoruba Proverbs

Page 1 / 12
(@obadelekambon)
Most BlackNificent Kmty! Admin

http://www.abibitumikasa.com/Owe%20Yoruba1.htm

<!---->
Òwe Yorùbá

<!---->
“Òwe Yorùbá jê gbólóhùn örö «ókí«ókí tí ó kún fún ìjìnlë ægbôn àti òye, tí ó sì jê ìrírí tí àwæn àgbààgbà ilë wa ti fi ÷nu kó jæ gêgê bí ëkô fún àwæn æmæ lêhìn wæn. Àwæn gbólóhùn örö «ókí«ókí wönyí kún fún ìtumö púpö, bí a bá sì lò wôn níbi tí ó y÷ kí a lò wôn, ìtumö ohun tí à bá fi örö púpö sæ yóò tètè yé ni yékéyéké.”
<!---->
“Òwe l’÷«in örö, bí örö bá sænù, òwe ni a fi ñ wá a.”
“Amöràn mæ òwe níí làjà öràn.”
<!---->

<!---->
<!---->
òwe - proverb
gbólóhùn – sentence
«ókí«ókí – very short
ìjìnlë ægbôn – deep wisdom
ìrírí - experience
àgbààgbà – elders
ilë – land
÷nu - mouth
kó jæ – gather together
ëkô – lessons
æmæ lêhìn wæn – descendants
lò – use
níbi – in the place
y÷ - to be proper
örö – word
tètè – quickly
yékéyéké - completely

Quote
Topic starter Posted : 24/08/2006 2:29 am
(@obadelekambon)
Most BlackNificent Kmty! Admin

Òtítô inú kìí sin 'ni ràjò k'á pàdánù.

Truthfulness does not join someone on a journey that we should suffer loss.

ReplyQuote
Topic starter Posted : 09/10/2006 10:37 pm
(@obadelekambon)
Most BlackNificent Kmty! Admin

Öb÷ t'ó mú kìí gbê èèkù ara rë.

A knife that is sharp (nevertheless) does not carve its own handle.

ReplyQuote
Topic starter Posted : 09/10/2006 10:41 pm
(@obadelekambon)
Most BlackNificent Kmty! Admin

"Igi gogoro má gún mi l'ójú" láti òkèèrè l'a ti ñ fæhùn.

"Sharp stick don't stick me in the eye", we say while it's still far away.
(Variation: "Igi gogoro má gún mi l'ójú" láti òkèèrè l'a ti ñ wò. (from a distance we look at it)

ReplyQuote
Topic starter Posted : 23/11/2006 6:13 pm
(@obadelekambon)
Most BlackNificent Kmty! Admin

Oníyangí má ba tèmi jê, epo ni mo rù.

Owner of small stones, don't spoil mine, I'm carrying red palm oil.

ReplyQuote
Topic starter Posted : 23/11/2006 6:20 pm
(@obadelekambon)
Most BlackNificent Kmty! Admin

Wôn fê sun ún j÷ têlë, ó ñ fepo para.

They already wanted to roast him and he's rubbing palm oil on himself.

ReplyQuote
Topic starter Posted : 23/11/2006 6:22 pm
(@obadelekambon)
Most BlackNificent Kmty! Admin

Örê ò gb÷lëta, Elèjì lörê gbà.

Friends do not make space for three. Two is what friends allow.

(From Èjì Ogbè, ÷s÷ ëk÷ta)

ReplyQuote
Topic starter Posted : 23/11/2006 6:26 pm
(@obadelekambon)
Most BlackNificent Kmty! Admin

Æmæ ÷ni ò «èdí jëõlëkë;
Ká fìlëkë sí tæmæ ÷lòmìíràn;
Æmæ ÷ni læmæ ÷ni jêThe backside of one's child is never so jacked up
That we would put Ileke onto that of someone else's child
One's child is who one's child is.

(From Èjì Ogbè, ÷s÷ ëk÷fà)

ReplyQuote
Topic starter Posted : 23/11/2006 6:35 pm
(@obadelekambon)
Most BlackNificent Kmty! Admin

¿nìkan ò gbædö na babaláwo.

One must not beat up a Babaláwo.

(From Öyëkú Méjì - ¿s÷ ëk÷fà)

ReplyQuote
Topic starter Posted : 23/11/2006 6:59 pm
(@obadelekambon)
Most BlackNificent Kmty! Admin

¿nu ÷y÷ ní í p÷y÷, ÷nu òfòrò ní í pòfòrò, òfòrò bímæ mêfà, ó ní ilé òun kún «ô«ô«ô:

It is the mouth of the bird that kills the bird, it is the mouth of the Squirrel, that kills the Squirrel, the Squirrel gives birth to 6, he brags that his house is completely full.

ReplyQuote
Topic starter Posted : 17/03/2007 1:47 pm
(@obadelekambon)
Most BlackNificent Kmty! Admin

Wôn ní, “Afôjú, æmæ ë p÷ran.” Ó ní kò dá òun lójú, àfi bí òún bá tô æ wò.

They said to the blind man, “Blind man, your son has killed a game.” He responds that he cannot believe them until he has tasted the meat.
(Always insist on proof positive.)

ReplyQuote
Topic starter Posted : 02/04/2007 4:01 pm
 Awotunde
(@Awotunde)

E se pupo for the proverbs. I truly appreciate the ones concerning the Odu. Also, it is funny I was just exlplaining to someone about how the squirrel is talked about in the Odu. The squirrel is ALWAYS talking and getting her/himself into trouble in the Odu Ifa.

ReplyQuote
Posted : 02/04/2007 11:54 pm
(@obadelekambon)
Most BlackNificent Kmty! Admin

Awotunde wrote: E se pupo for the proverbs. I truly appreciate the ones concerning the Odu. Also, it is funny I was just exlplaining to someone about how the squirrel is talked about in the Odu. The squirrel is ALWAYS talking and getting her/himself into trouble in the Odu Ifa.


Kò tôpê rárá! Òótô ni. Òfòrò sábà máa ñ forí jálé agbôn! It's true. The squirrel often runs his head into the wasps' nest!

Æbádélé

ReplyQuote
Topic starter Posted : 06/04/2007 12:48 pm
(@obadelekambon)
Most BlackNificent Kmty! Admin

Bí onígbàá bá fi ìgbá rë dá àìkàràgbá, æmæ aráyé á bá a fi kó ilë.

When the owner of the calabash makes her or his calabash into a cracked calabash, the citizens of the world will join her or him in using it to gather dirt.
(If you don't value your own things, neither will anyone else)

ReplyQuote
Topic starter Posted : 06/04/2007 12:51 pm
(@obadelekambon)
Most BlackNificent Kmty! Admin

Bí oore bá pö lápöjù, ibi ní í dà.

When generosity becomes too much, it often begets ingratitude (wickedness).

ReplyQuote
Topic starter Posted : 06/04/2007 1:07 pm
Page 1 / 12

Leave a reply

Author Name

Author Email

Title *

 
Preview 0 Revisions Saved
Share:

X
X
X
X