

johndavis30112
-
-
Láká-láká ò ṣéé fi làjà; ọmọ eégún ò ṣéé gbé ṣeré.
A limp is no great asset for a person wish- ing to stop a fight; a masquerader’s child is no easy playmate. (One should know one’s limits and also what one would be ill advised to attempt.)‘‘Mo mò-ó tán’’ lOrò-ó fi ńgbé ọkùnrin.
‘‘I know it all’’ is the reason for Orò’s carry-
ing…-
88,678 Abibisika (Black Gold) Points
Ilẹ̀ kì í gba ọ̀gẹ̀dẹ̀ k’ó so ìdì méjì.
The soil is never so nourishing for the banana plant that it brings forth two bunches at once. (Nature places limits on everyone and everything.)
-
-
-
-