Group Feed
-
omoyeijoba posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago
A kì í tóó bánigbé ká má tòó r-bánisọ. One does not qualify to live with a person without also qualifying to talk to the person.Akì í bá ẹni gbé ká má mọ ojú ẹni. One does not live with a person and yet not know how to deal with him or her.
.Aṣenilóde ò tó tilé; ilé ni wn ti ńṣeni.The enemy outside is no match for the enemy…
-
99,228 Abibisika (Black Gold) Points
Oníwàpẹ̀lẹ́: a-báni-gbé-tuni-lára.
A mild-mannered person [is] one with whom cohabitation envelops one in ease. (A mild-mannered person is a joy to live with.)
-
-
-
johndavis30112 posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago
Láká-láká ò ṣéé fi làjà; ọmọ eégún ò ṣéé gbé ṣeré.
A limp is no great asset for a person wish- ing to stop a fight; a masquerader’s child is no easy playmate. (One should know one’s limits and also what one would be ill advised to attempt.)‘‘Mo mò-ó tán’’ lOrò-ó fi ńgbé ọkùnrin.
‘‘I know it all’’ is the reason for Orò’s carry-
ing…-
99,228 Abibisika (Black Gold) Points
Ilẹ̀ kì í gba ọ̀gẹ̀dẹ̀ k’ó so ìdì méjì.
The soil is never so nourishing for the banana plant that it brings forth two bunches at once. (Nature places limits on everyone and everything.)
-
-
-
Okunini Ọbádélé Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago
99,228 Abibisika (Black Gold) Points
“Tí ọmọdé bá ní aṣo bíi àgbà, kò lè ní àkísà tó àgbà” (Ademowo & Balogun, 2014)
English: “If a child has clothes like the old, he cannot have more rags than the old”.
Experience is the best teacher. - Load More