Group Feed
-
-
-
Ɔbenfo Ọbádélé posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 6 years ago
99,988 Abibisika (Black Gold) Points
Tọ́jú ìwà rẹ ọ̀rẹ́ mi
Ọlá a máa ṣí lọ nílé ẹni
Ẹwà a sì máa ṣí lára ènìyàn
Ṣùgbọ́n ìwà ní í bá ‘ni dé sàárèÈéfín nìwà, rírú ní í rú
Ènìyàn gb’ókèèrè níyì
Ṣùgbọ́n súnmọ́ ni, l’a fi ń mọ̀’ṣe ẹni
Ìwà kò ní í foníwà sílẹ̀Ìwà ọmọ l’ó ń sọmọ lórúkọ
Ọmọ dára ó ku ìwà
Ara dára ó ku aṣọ
Ẹsẹ̀ dára ó ku… Read more -
-
- Load More