-
98,518 Abibisika (Black Gold) Points
Wọ́n ní, ‘‘Afọ́jú, ọmọ rẹ pẹran.’’ Ó ní kò dá òun lójú, àfi bí òun bá tọ́ ọ wò.
They said to the blind man, ‘‘Blind man, your son has killed game.’’ He responds that he cannot believe them until he has tasted the meat. (Always insist on positive proof.)-
Ẹni ìjà ò bá ní ńpe ara ẹ́ lọ́kùnrin.
It is the person not faced with a fight who boasts about his manliness.
(One can always boast when one is certain there will be no need for proof.)-
98,518 Abibisika (Black Gold) Points
Aláǹgbá kì í lérí àti pa ejò.
A lizard does not boast that it will kill a snake. (People should not propose what they cannot accomplish.)-
Aláàńtètè: ó jí ní kùtùkùtù ó ní òun ó dàá yànpọ́n-yànpọ́n sílẹ́.
The cricket arises in the morning and vows to perform wonders. (The puny person’s boasts are always empty.)
-
-
-