-
Bí a kò bá lówó aládìn-ín, a jẹun lójúmọmọ, à gbálẹ̀ sùn wàrà.
If one has no money for lamp oil, one eats in the daytime and sweeps the house and goes to sleep in good time. (One’s plans and actions should fit one’s resources.)
“Yán sí i, yán sí i” ní ńpa alákàrà lẹ́ rìn-ín.
“Sell more to me, sell more to me” is what brings smiles to the face of the bean-fritters seller. (Good fortune always makes people happy.)
-
Mema wo awodapa Ama,
Tweduampɔn ɛne Nananom nyɛ who kɛseɛ na wɔnma wo ahuɔden a wode bɛtoa Abibiman fahodie ɔko yi ho.
❤️🖤💚
-