-
Bí ọmọdé ò bátàn, yòó bá àrọ́bá…
Èyí ni ìtàn ìgbé ayé Aarẹ ọna Kakanfo ilẹ̀ Yorùbá, Afonja tí ìtàn sọ pé nípasẹ̀ rẹ̀ ni Ilorin fi bọ́ mọ́ Yorùbá lọ́wọ́.
Se uma criança não engana, enganará desviado..
Esta é a história de vida do presidente de Kakanfo de Yoruba, Afonja, cuja história diz que Ilorin foi enterrado por Yoruba.
bbc.in
Wò ó bí Afọnja ṣe finú wénú tí Ilọrin fi bọ́ mọ́ Yorùbá lọ́wọ́ - BBC News Yorùbá
Eyi ni itan igbe aye Aarẹ Ọna Kakanfo Afọnja ilẹ Yoruba to wa ni Ilorin, ẹni to fi inu wenu pẹlu Fulani, amọ to jẹ iwọ.