Group Feed
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
Bí ògiri kò lanu, aláǹgbá kò lè ráyè wọbẹ̀.
If the wall does not open its mouth the lizard will never be able to enter it. -
-
Okunini Ọbádélé Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
98,498 Abibisika (Black Gold) Points
Wọ́n ní, ‘‘Afọ́jú, ọmọ rẹ pẹran.’’ Ó ní kò dá òun lójú, àfi bí òun bá tọ́ ọ wò.
They said to the blind man, ‘‘Blind man, your son has killed game.’’ He responds that he cannot believe them until he has tasted the meat. (Always insist on positive proof.)-
Ẹni ìjà ò bá ní ńpe ara ẹ́ lọ́kùnrin.
It is the person not faced with a fight who boasts about his manliness.
(One can always boast when one is certain there will be no need for proof.)- View 2 replies
-
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
A kì í gbin àlùbọ́sà, kó hu ẹ̀fọ́, ohun tí ènìyàn bá gbìn ni yóò ká.
You cannot sow onions and reap vegetables; whatever a man sows, he shall reap.
-
98,498 Abibisika (Black Gold) Points
Ẹ káre! Inú mi dùn.
-
98,498 Abibisika (Black Gold) Points
Bí ojú kò pọ́nni bí osùn, a kì í he ohun pupa bí idẹ.
If one’s eyes do not become as red as camwood stain, one does not come by something as red as brass. (Unless one endures some hardship, one does not reap great benefits.)- View 1 reply
-
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
Bí a ṣe ń kọ́’ṣẹ́ ni à ń kọ́ ìyàra.
As we learn a job, so also we learn fastness.-
98,498 Abibisika (Black Gold) Points
Ìyàra tàbí ìyára? -
98,498 Abibisika (Black Gold) Points
A níṣẹ́ iṣẹ́ ẹ, o ní o ń lọ sóko; bó o bá lọ sóko o ń bọ̀ wá bá a nílé.
You are told that a job is your responsibility, and you say you are on your way to the farm; you may be on your way to the farm, but the job will be there on your return. (One may devise stratagems to defer carrying out one’s duties, but they are unlikely to make…
-
- Load More