Group Feed
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
Àdán doríkodò, ó ń wo ìṣe Ẹyẹ.
The bat hangs upside down, watching the deeds of the birds.-
99,148 Abibisika (Black Gold) Points
Àdán sọ orí kodò, ó ń wòṣe ẹyẹ gbogbo.
The bat hangs its head and contemplates the doings of birds. (The quiet person sees more than the loudmouth.)
-
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
Afọ́jú tó bá ará ilée rẹ̀ jà yóò kọ lu ògiri pẹ́.
A blind man that quarrels with those he lives with will bump into walls for long.
-
99,148 Abibisika (Black Gold) Points
Ìṣẹ́ kì í mú ọkọ mú aya kó má ran ọmọ.
Suffering does not grip the husband and grip the wife but spare the child. (The dependent cannot escape the hardship that befalls his or her benefactors.)
-
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
A gb’ẹ́jọ́-ẹnìkan-dá, àgbà òṣìkà ni.
One who judges based on one side of the story is a wicked elder.-
99,148 Abibisika (Black Gold) Points
Akọ́kọ́dájọ́ lọ̀tá ẹlẹ́jọ́.
The first judge is the enemy of the litigant.
(Few people take criticism kindly.)
-
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
Àìmọ́nú í rò ni àìmọ ọpẹ́ í dá.
Inability to reflect is inability to give thanks.-
99,148 Abibisika (Black Gold) Points
Òrìṣà ní ńpeni wá jẹ ọkà; a kì í gbọ́ ọwọ́ orógùn lẹ́hìnkùlé.
It is the Òrìṣà that summon one to come eat yam-flour meal; one does not hear the sound of the stirring stick from the back
-
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
Àìjẹun Ológbò kọ́ ni kò jẹ́ kó t’Ájá, bí wọ́n ti ń mọ ní ìran Esé ni.
It is not due to fasting of the cat that it is not as big as the dog, it is just the size of its race.-
99,148 Abibisika (Black Gold) Points
Màlúù ò lè lérí níwájú ẹṣin.
A cow may not boast in the presence of a horse. (One should acknowledge and defer to those better able than oneself.)
-
- Load More