Group Feed
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
Àṣírí ẹ̀kọ́ kò ní tú lójú ewé.
The cornmeal’s secret will never be revealed in the presence of the leaf.-
99,158 Abibisika (Black Gold) Points
ẹ̀kọ kìí ṣe ẹ̀kọ́ -
99,158 Abibisika (Black Gold) Points
Àṣírí ìkokò, ajá kọ́ ni yóò tú u.
The secrets of the hyena’s being will not be revealed through the actions of the dog.
(The stalwart’s comeuppance will not happen at the hands of a no-account person.)
-
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
Aṣọ ńlá kọ́ l’ènìyàn ńlá.
Wearing a big cloth doesn’t make one a big person-
99,158 Abibisika (Black Gold) Points
O ru ládugbó ò ńrera; kí ni ká sọ fẹ́ni tó ru Òrìṣà-a Yemọja?
Because you are carrying a huge pot, you strut; what would one say to the person carrying the divinity Yemoja? (Never assume that you are more important than you actually are, especially when there are really more important people around.)
-
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
Bí a bá ju abẹ̀bẹ̀ s’ókè nígbà igba, ibi pẹlẹbẹ ni yóò fi lé’lẹ̀.
If we throw a fan upwards for two hundred times, it will always land on a flat surface. -
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
Bí bínibíni kò bá bí-ni, mọnimọni kò lè mọ-ni.
If the one who gave birth to you did not give birth to you, those who know you will not know you. -
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
Awífúnni kó tó dá-ná, àgbà ìjàkàdì ni.
One who warned you beforehand and still overpowered you, is a great wrestler. - Load More