Group Feed
-
Ukweli Imana posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago
Igi so so o y’a a ghonen ‘ju, a to ke iye e ti ho i.
Translation: The pointed stick that will pierce one in the eye, is avoided while it is still far off.
Meaning: To be forewarned, is to be forearmed.-
99,198 Abibisika (Black Gold) Points
Igi ganganran má gùn-ún mi lójú, òkèèrè la ti ńwò ó wá.
‘‘Protruding twig, do not poke me in the eye’’; one must keep one’s eyes on the twig from a distance. (Don’t wait until problems arise before preparing to deal with them.)
-
-
Ukweli Imana posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago
Adìẹ funfun kò mọ ara rẹ̀lágbà
Translation: The white chicken does not realize its age
Meaning: Respect yourself-
99,198 Abibisika (Black Gold) Points
Àgbà tí kò nítìjú, ojú kan ni ìbá ní; ojú kan náà a wà lọ́gangan ìwájú-u rẹ̀.
An elder without self-respect might as well have only one eye, that one eye being in the center of his forehead. (Shamelessness does not become an elder.)
-
-
Aum Amen Ra posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago
Máà gbédn yún óko,àíké orí ó tóó lagi[Don’t carry an axe to the farm,the axe on his head will do for splitting wood.]-
99,198 Abibisika (Black Gold) Points
Ẹ̀rúkọ́, orí aaka; ẹ̀rú àáké, orí aaka; aaka nìkan nigi tó wà nígbó ni?
For a haft for the hoe, the choice is the aaka tree; for a haft for the axe, the choice is the aaka tree; is the aaka tree the only one in the forest? (A person should not be the one to whom every offense or crime is traced.)
-
-
-
Titilayo Olayinka posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago
Adì ńjẹkà, ó ḿmumi, ó ńgbé òkúta p -p-p mì, ó ní òun ò léhín; ìdérègbè tó léhínńgbé irin mì bí? The chicken eats corn, drinks water,…-
99,198 Abibisika (Black Gold) Points
O káre l’áyé!!! -
99,198 Abibisika (Black Gold) Points
Ẹni tí a bá ńdáṣọ fún kì í ka èèwò.
The person who is clothed by others does not list what he will not wear. (Those who depend on the charity of others must be satisfied with whatever they can get.- View 27 replies
-
99,198 Abibisika (Black Gold) Points
@amalove805, note that pasting ẹ ẹ́ and ẹ̀ as well as ọ ọ́ and ọ̀ don’t show up correctly, so you have to type those in manually. O ṣé
-
- Load More