Group Feed
-
Omisola Omowale posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago
[Person 1]
Akìífioríwéoríi Mo kúṣiré; bí Mokú kú láàár a jí lál .
-One does not liken one’s fortune to Mokú-ṣiré’s; if Mokú dies in the morning, he resurrects at night.
(Never emulate people who
know tricks you don’t.)[Person 2]
A di gàárì síl ewúr ńyọjú; ẹrù ìran r ni?
-We prepare the saddle, and the goat presents itself;…-
99,198 Abibisika (Black Gold) Points
A ní k’á wá ẹni t’ó l’ẹ́hìn k’á fọmọ fún, abuké ní òun rèé; ti gànnàkù ẹ̀hìn-in rẹ̀ là ń wí?
One seeks a person with a prominent back as suitor for one’s daughter, and the hunchback presents himself; who spoke of a protruding back? (Since the expression that translates as ‘‘prominent back’’ is an idiom
meaning a proud pedigree. the…
-
-
-
Ewuradjoa Naa Norley Newman posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago
-
Khepra Osagyefo posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago
A kì í yàgò fún ‘‘Mo gun ẹṣin rí o!’’
One does not get out of the way for ‘‘I used
to ride a horse!’’ (People should not expect
to live on past glory.)-
99,198 Abibisika (Black Gold) Points
A kìí yàgò fún ẹlẹ́ṣin àná. One doesn’t get out of the way of the owner of yesterday’s horse.
-
-
Khepra Osagyefo posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago
A kì í peni lákọ ẹran ká ṣorí bòró.
One does not enjoy the designation ‘‘He
Goat’’ and yet sport a smooth [hornless]
head. (A person should live up to his or her
billing.)-
99,198 Abibisika (Black Gold) Points
Ibi a bá pè lórí ní ń hurun.
It is the place named the head that grows hair. (People and objects should live up to expectations.)
-
- Load More