-
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
A kì í gb’ókèèrè mọ̀ dídùn ọbẹ̀.
You cannot stay at a distance and know how sweet a soup is.-
98,518 Abibisika (Black Gold) Points
Òótọ́ ni!
-
98,518 Abibisika (Black Gold) Points
Bánidélé l’a ń mọ ìṣe ẹni; Èèyàn gbé òkèèrè níyì
[Going home with a person is how one knows his or her ways; People enjoy good repute when they live at a distance]-
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
Ilé la ti ń kó ẹ̀ṣọ́ ròde. Charity begins at home.
-
98,518 Abibisika (Black Gold) Points
Ọmọ tí a kò bá kọ̣́ gbélé t’a bá kọ́ tà. The child that we don’t teach sells the house that we built.
-
-
-