-
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
A kì í mọ ìwà ilẹ̀ kó kú ni’ṣu.
Once you know the features of a soil, it will not stunt your yam.-
99,148 Abibisika (Black Gold) Points
Ọjọ́ tí àgbẹ̀ ṣíṣe-é bá di kíyèsílẹ̀, ká ṣíwọ̀
oko ríro.
The day farming entails being careful not to hurt the soil, one should stop farming.
(If the basic condition for a trade is interdicted, one should no longer engage in that trade.)
-