-
14,010 Abibisika (Black Gold) Points
A gb’ẹ́jọ́-ẹnìkan-dá, àgbà òṣìkà ni.
One who judges based on one side of the story is a wicked elder.-
99,198 Abibisika (Black Gold) Points
Akọ́kọ́dájọ́ lọ̀tá ẹlẹ́jọ́.
The first judge is the enemy of the litigant.
(Few people take criticism kindly.)
-