-
14,010 Abibisika (Black Gold) Points
Àsìkò ara là ń búra, ẹnìkan kì i bú Ṣàngó nígbà èèrùn.
You have to swear at the appropriate time, one cannot swear by Ṣàngó during the dry season.-
99,158 Abibisika (Black Gold) Points
Ẹnu ehoro ò gba ìjánu.
A rabbit’s mouth does not accept a bridle. (Do not adopt an inappropriate remedy for a problem.)
-