-
14,010 Abibisika (Black Gold) Points
Asọ̀kò fún igba Adìẹ òkò ni yóò sọ tílẹ̀ fi ṣú.
he who throws stones at two hundred fowls will throw them till sunset.
-
99,198 Abibisika (Black Gold) Points
Ẹni tó yínbọn sí ahoro, ó ti mọ̀ pé alámù lòun óò rí pa níbẹ̀.
The person who shoots a gun into a deserted house knows that he will kill only lizards therein. (A person who engages in a pointless gesture is reconciled to emptiness.)
-