-
98,588 Abibisika (Black Gold) Points
Ògbójú ò tẹ ara ẹ̀ nÍfá; ọ̀mọ̀ràn ò fara ẹ̀ joyè; ọ̀bẹ tó mú ò gbẹ́ ẹ̀kù ara ẹ̀.
The intrepid person does not consult the Ifá oracle on his own behalf; the sagacious person does not enthrone himself; the sharpest knife does not carve its own hilt. (No matter how powerful and accomplished one might
be, one will need other people for some things.)