-
88,828 Abibisika (Black Gold) Points
(1) Orúkọ ọmọ ni ìjánu ọmọ ‘A child’s name is his/her brake’
(2) Orúkọ níí ro ọmọ ‘A child is influenced by his/her name’
(3) Orúkọ ìsọ ọmọ níí mọ́ ọmọ l’ára ‘A child gets used to behaving like his/her name’
(4) Ọmọ asẹ́gità tí ń ta èèpo igi, orúkọ l’ó ń rò ‘The child of wood dealer who sells wood’s bark is influenced by his/her name.’