-
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
A gún ata l’ódó, a lọ ata l’ọ́lọ, ìwà ata kò padà.
Even after pounding and grinding, pepper will still remain pepperish.
-
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
This proverb reminds me of Nana Ọmọwálé Malcolm X’s famous statement about how the kitten will never be a biscuit.
A pepper is a pepper, an Afrikan is an Afrikan.
-
98,588 Abibisika (Black Gold) Points
Bí iyán ti ń fun lóko ẹgàn, bẹ́ẹ̀ náà níí ń fun ní ti etílé.
As pounded yam is white on a farm deep in the forest, so it is white on the farm near the town. (A commodity does not change its nature according to its location.)
-
-
98,588 Abibisika (Black Gold) Points
Ẹ káre. Bí ó ti wù kí ó rí, Adúláwọ̀ jẹ́ Adúláwọ̀.
-