-
88,768 Abibisika (Black Gold) Points
“Ìwà lòrìṣà; bí a ti hù ú sí ní ń gbeni sí”. (Adebayo, 1979:57)
English: “Character is a god; just as one lives it, so it supports one”.
(“One’s fortune depends on one’s character.”)
-
Ànán-mánàán ẹtú jìnfìn; oní-mónìí ẹtú jìnfìn; ẹran mìíràn ò sí nígbó lhìn ẹtu? Yesterday the antelope was caught in a pit trap; today the antelope is caught in a pit trap; is there no other animal in the forest besides the antelope? (If the same person repeatedly finds himself or herself in difficulties others are able to avoid, one should look to the person’s character for the explanation.)
-
Bí a ó ti tó kì í je ká hùwà búburú; bí a ó ti mọ kì í je ká hùwà rere.
The heights one will reach keep one from evil deeds; the ordained limit to one’s great-ness keeps one from doing good deeds.
(A person’s achievements are enhanced or limited by the person’s character.)-
88,768 Abibisika (Black Gold) Points
Àgbà òṣìkà ńgbin ìyà sílẹ̀ de ọmọ-ọ rẹ̀.
A wicked elder sows suffering for his children.
(One’s character often affects the fortunes of one’s children.)-
Àgbà kán ṣe béé lÓgùn; Yemaja ló gbé elọ.
An elderly person tried it [something] in the river Ògùn; the river goddess carried him away. (Thoughtless emulation of others could be disastrous.)
-
88,768 Abibisika (Black Gold) Points
Oore kì í gbé; ìkà kì í dànù; à-ṣoore jindò ní ń múni pàdánù oore.
A good deed does not go for nought; a wicked deed is never lost; drowning while doing a favor is what makes the good person lose out on the rewards for his goodness. (Every kindness, like every wickedness, is rewarded; one should be prudent, though, in doing favors.)
-
-
-
-
-
A kì í fi òtító sínú gbàwìn ìkà.
One does not leave truthfulness inside to purchase wickedness on credit.
(Never go out of your way to injure others.)-
88,768 Abibisika (Black Gold) Points
Oníkùn ló mọ̀kà; oníbàntẹ́ ló moye òun-ún dì sí i.
The owner of the stomach alone knows what wickedness lurks inside; the owner of the loin money pouch alone knows how much money she has tied up in it. (No one knows what secret lies buried inside other people.)
-
-