-
88,768 Abibisika (Black Gold) Points
“Igi ganganran má gún mi lójú, òkèèrè làá ti ń yẹ̀ ẹ́”. (Delano, 1976:127)
English: “For a dangerous stick not to stick me in the eye, I must endeavour to dodge it from afar.” (“Don’t wait until problems arise before preparing to deal with them.”)
-
88,768 Abibisika (Black Gold) Points
‘‘Ó ḿbo, ó ḿbo!’’ ẹ̀wọ̀n là ń so sílẹ̀ dè é.
‘‘Watch out, watch out, for here it comes!’’ For such a thing one would best prepare a snare.
(If the thought of something fills one with apprehension, one should plot to defeat it.) -
88,768 Abibisika (Black Gold) Points
Nítorí adití lòjó fi ń ṣú; nítorí afọ́jú l’ó ṣe ń kù.
It is for the benefit of deaf people that rain clouds gather; it is for the benefit of the blind that thunder rumbles. (The wise person should be able to read portents and take precautions.)-
Ọgbọ́n ọdúnnìí, wèrè ẹ̀míì. Today’s wisdom, next year’s madness. (What seems wise now may appear like lunacy in hindsight.)
-
88,768 Abibisika (Black Gold) Points
Àṣìṣe ò kan ọgbọ́n.
Mistakes have nothing to do with wisdom.
(To be mistaken is not necessarily to be unwise.)-
Ẹyin adìẹ ò gbọdọ̀ forí sọ àpáta. A chicken egg should not strike its head against a rock.(It is unwise to take on forces one cannot withstand.)
-
88,768 Abibisika (Black Gold) Points
Kò sí ohun tí ń ti òkè bọ̀ tí ilẹ̀ ò gbà.
There is nothing dropping from above that the earth cannot withstand. (There is no eventuality that one cannot cope with.) -
Bí ìdí ìkokò kò bá dá a lójú, kì í gbé egungun mì. If the wolf does not have faith in its anus, it does not swallow bones. (One should not attempt a thing whose repercussions one cannot withstand.)
-
88,768 Abibisika (Black Gold) Points
Ẹni tí ò tóni-í nà ò gbọdọ̀ ṣe kọ́-ń-dú síni.
A person who is not strong enough to beat you up should not adopt a threatening pose toward you. (People should not challenge forces they cannot withstand.) -
Ọmọdé ní wọ́n ńjẹ igún, bàbá ẹ̀-ẹ́ níwọn kì í jẹ; ó ní ẹnìkán jẹ rí lójú òun; bàbá ẹ̀-ẹ́ nítani?Ó ní ẹni náà ò sí. A child says that people do eat vultures, and its father says people do not; the child says someone did eat a vulture in its presence; its father asks, who?The child says the person is dead. (The youth who attempts to challenge the wisdom of the elders will find himself tripped up by his own mouth.)
-
88,768 Abibisika (Black Gold) Points
Bí ọmọdé bá mọ ayò, ẹyọ la ó fi pa á.
If a child is an adept ayò player, one defeats him with single seeds. (A precocious child may be almost but not quite as accomplished as an adult.) -
Ọmọ tí yó jẹ̀ẹ́ àṣàmú, kékeré ní ńtií ṣẹnu ṣámú-ṣámú. A person who will become exemplary begins showing precociousness from childhood. (Childhood shows the adult.)
-
88,768 Abibisika (Black Gold) Points
Òwúrọ̀ la ti ń mọ bí alẹ́ yóò ti sanni sí.
It is from the morning that one knows how good one’s night will be. (From youth one can tell how pleasant one’s old age will be.) -
A pèèpò lẹ́hìn àgbà, àgbà ḿbọ̀ wá.You who clear the weeds behind an elder, your old age approaches. (Those who do favors for old people should be reminded that they too will some day grow old.)
-
88,768 Abibisika (Black Gold) Points
Ogbó ò lóògùn.
Aging has no antidote. (We all grow old, no matter what) -
Irun dúdú ní ńṣíwájú ewú. Black hair is the forerunner of white hair. (Old age comes inexorably after youth.)
-
88,768 Abibisika (Black Gold) Points
Ká kú ní kékeré ká fẹṣin ṣe ìrẹ̀lẹ̀ ẹni, ó sàn ju ká dàgbà kú láìní adìẹ ìrẹ̀nà.
To die young and have a horse sacrificed to ease one’s passage to the beyond is better than to reach old age before dying but with not even a chicken sacrificed to ease one’s passage. (Better to die young and prosperous than to die old and destitute.) -
Ò ńjàgbọ̀nrín èṣín lọ́bẹ̀, o ní o ti tó tán.You are reduced to eating last year’s antelope in your stew, and yet you claim to have attained the height of good fortune. (A hard-up person who claims to be prosperous deceives himself or herself.)
-
88,768 Abibisika (Black Gold) Points
Àtẹ́lẹwọ́ ẹni kì í tanni.
One’s palm does not deceive one. (One’s trust is best placed in one’s own resources.)
-
-
-
-
-
A kì í bá ọba pàlà kí ọk ọba má ṣàn-ánnils. . (One should be cautious in dealing with people in authority.
-
88,768 Abibisika (Black Gold) Points
@rayven-custis, you have to type in the letters that aren’t pasted in correctly. Otherwise, it won’t show up right. -
88,768 Abibisika (Black Gold) Points
Ẹ̀bìtì ò peèrà tó ṣe pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́; ẹnu ẹni ní ń pani.
A trap does not kill an ant that is cautious; it is one’s mouth that turns out to be one’s death. (The cautious will live long on the earth; the incautious engineers his or her own death.)
-
-
A kì í bínú ààtàn ká dal sígb. (One should not act in unreasonable and harmful ways because of anger.)
-
88,768 Abibisika (Black Gold) Points
A kì í bínú orí ká fi fìlà dé ìbàdí.
One does not get angry with one’s head and therefore use one’s cap to cover one’s buttocks.
(Do not cut off your nose to spite your face.)
-
-
A kì í brù ikú brù àrùn ká ní kí ọmọ ó kúsinni. (One should not be more concerned with saving oneself than with saving one’s dependents.)
-
88,768 Abibisika (Black Gold) Points
A kì í dàgbà má làáyà; ibi ayé bá báni là ń jẹ ẹ́.
One does not become an adult and yet lack courage; one lives life as it finds one. (One should do what is fitting for one’s station in life.)-
Arúgbó ẹrú ò jẹ́ ọ̀fẹ́; òtòṣì ọba ò singbà; ìwọ̀fà kan ò dàgbà dàgbà kó ní òun ò sinolówó mọ́. An old slave does not go for nothing; a poor king does not pawn himself; however old a pawn may be, he may not refuse to serv ethe creditor. (Every station has its obligations and its limits; prosperity, poverty, and duties are relative to one’s position.)
-
88,768 Abibisika (Black Gold) Points
Àbúrò kì í pa ẹ̀gbọ́n nítàn.
The younger person does not give the older person history lectures. (One should not exceed one’s station.)
-
-
-
-