-
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
A kì í mọ ẹsẹ̀ òṣìkà lójú ọ̀nà.You cannot differentiate the wicked’s footprints in the road.
-
99,148 Abibisika (Black Gold) Points
O rí ẹsẹ̀-ẹ wèrè o ò bù ú ṣoògùn; níbo lo ti máa rí tọlọ́gbọ́n?
You see the footprint of an imbecile and you do not take soil from it to make a charm; where will you find the footprint of a wise person?
-