-
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
A kì í rí oko lóko ikún, ká tún gbin ẹ̀pà sí i.
You should not see a farm inhabited by squirrels and still plant nuts in it.-
99,148 Abibisika (Black Gold) Points
Àjàpá ní kò sí ohun tó dà bí ohun tí a mọ̀ ọ́ ṣe; ó ní bí òun bá ń rìn l’óko ẹ̀pà, ọ̀kọ̀ọ̀kan á
máa bọ́ sóun l’ẹ́nu. Tortoise says there is nothing quite like what one knows how to do; it says when it walks through a peanut farm, peanuts keep popping one by one into its mouth. (When one does what one is a true expert at doing, it seems like performing magic.)
-