-
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
Abèèrè ọ̀nà kì í ṣìnà.
He who asks for directions does not miss his way.-
99,148 Abibisika (Black Gold) Points
K’á wí fún ẹni k’á gbọ́; k’á sọ̀rọ̀ fúnni k’á gbà; k’á bèèrè ọ̀nà lọ́wọ́ èrò t’ó kù l’ẹ́hìn k’áyé baà lè yẹni.
If one is spoken to, one should listen; if one is advised, one should heed the advice; one should seek direction from wayfarers who are behind one in order that one’s life might be pleasant. (It is wise to heed advice, and it is wise to seek direction from those who have greater experience.)
-