-
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
Àròkàn l’ó ń m’ẹ́kún àsun ì dá wá.
The anguish of the mind brings about endless crying.-
99,158 Abibisika (Black Gold) Points
Ó yé ọmọ tí ń sunkún, ó sì yé ìyá ẹ̀ tí ḿbẹ̀ ẹ́.
The crying child knows why it is crying, and the mother consoling it knows why she is doing so. (Each person is privy to the motivation for his or her actions.)
-