-
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
Bí a bá ní ká di’jú kí ẹni búburú kọjá, a kò ní mọ ìgbà tí ẹni rere yóò kọjá.
If one decides to close his eyes for the bad person to pass, one will not know when a good person will pass by.
-
99,148 Abibisika (Black Gold) Points
Bí a bá rí èké, à ṣebí èèyàn rere ni; à sọ̀rọ̀ ságbọ̀n a jò.
When one sees a devious person, one mistakes him for a good person; one talks into a basket and it leaks. (It is easy to mistake a bad person for a good one and to place trust in that person.)
-