-
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
Bí a ṣe ń kọ́’ṣẹ́ ni à ń kọ́ ìyàra.
As we learn a job, so also we learn fastness.-
98,518 Abibisika (Black Gold) Points
Ìyàra tàbí ìyára? -
98,518 Abibisika (Black Gold) Points
A níṣẹ́ iṣẹ́ ẹ, o ní o ń lọ sóko; bó o bá lọ sóko o ń bọ̀ wá bá a nílé.
You are told that a job is your responsibility, and you say you are on your way to the farm; you may be on your way to the farm, but the job will be there on your return. (One may devise stratagems to defer carrying out one’s duties, but they are unlikely to make others carry them out.)
-