- 
	
	Atikaresete, awo orun A difa fun Oludumare ati aye Nigbati awon omo-araye nsare to Oludumare nitori ohun gbogbo Nke Baba, Baba, mo de Gba mi; jowo gba mi Oludumare ni: eetiri? Eniti mo fun l’ogbon ko lo agbara Eniti mo fun l’ogbon ko lo ogbon won ti mo fun won. Won ni awon omo ti ko ri awon obi won Won maa Sa ipa inu won ……. Atikaresete, the self-adjuster, the priest of heaven, Interpreted the teachings of Ifa for Oludumare and the world, When the people of the world were running to Oludumare for everything, Crying out “Baba, Baba, I have come. Save me; please save me.” Oludumare said: “What is the matter? Those whom I have given wisdom do not use their ability. And those whom I have given wisdom do not use the wisdom I have given them.” It is said: children who do not see their parents, will strive for their own inner strength. – Iwori Osa, Odu Ifa 
 
		 
				 
				 
                         
                         
			