Description
Learn-At-Your-Own-Pace Conversational Yoruba Class [Offline]
To view a sample page of lesson one, please visit: sampleyorubasampleyoruba
Ètò Ẹ̀kọ́ Yorùbá Alákọ́bẹ̀rẹ̀
Introductory Yorùbá Course Syllabus
Ẹ̀kọ́ Kìíní (1st Lesson): Pípè ìró èdè Yorùbá (Pronounciation of the sounds of Yorùbá); Àwọn Ọ̀rọ̀ Tuntun (New Words); Àwọn Àmì Ohùn Yorùbá (Yoruba Tones)
Ẹ̀kọ́ Kejì (2nd Lesson): Ìkíni Ìlera Yorùbá (Yorùbá greetings asking after health); Ìkíni láàrin Ọjọ́ (greetings for times of day)
Ẹ̀kọ́ Kẹta (3rd Lesson): Orúkọ rẹ (Your name)
Ẹ̀kọ́ Kẹrin (4th Lesson): Ibí tí o ti wá (The place you’re from); Ibí tí o ń gbé (The place you live)
Ẹ̀kọ́ Karùnún (5th Lesson): Nǹkan tí o fẹ́ (That which you like)
Ẹ̀kọ́ Kẹfà (6th Lesson): Nǹkan tí o máa ń ṣe (That which you do)
Ẹ̀kọ́ Keje (7th Lesson): Ọjọ́ orí (Your age); Àpèjúwe ara ẹni (Description of oneself)
Ẹ̀kọ́ Kẹjọ (8th Lesson): Ìdánwò Yorùbá (Yorùbá Exam) Iṣẹ́ Ìparí (Work on final projects)
Take advantage of the best opportunity to learn Yoruba at your own pace in the Afrikan world!
Reviews