Group Feed
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
A gún ata l’ódó, a lọ ata l’ọ́lọ, ìwà ata kò padà.
Even after pounding and grinding, pepper will still remain pepperish.
-
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
This proverb reminds me of Nana Ọmọwálé Malcolm X’s famous statement about how the kitten will never be a biscuit.
A pepper is a pepper, an Afrikan is an Afrikan.
- View 1 reply
-
98,548 Abibisika (Black Gold) Points
Ẹ káre. Bí ó ti wù kí ó rí, Adúláwọ̀ jẹ́ Adúláwọ̀.
-
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
A kì í gbé’lé ẹní, ká f’orùn rọ́.
You do not stay in your house and break your neck.
-
98,548 Abibisika (Black Gold) Points
Ilé-ni-mo-wà kì í jẹ̀bi ẹjọ́.
‘‘I-was-in-my-home’’ is never the guilty party in a dispute. (One does not get into trouble by minding one’s own business.)
-
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
A kì í fi iṣẹ́ ìgbọ̀nsẹ̀ rán ọmọ ẹni.
Defecation is an errand that one cannot send one’s child.-
98,548 Abibisika (Black Gold) Points
Ẹ káre. Àwọn méjì yòókù ńkọ́?
-
98,548 Abibisika (Black Gold) Points
Adáramáṣu ò sí.
There is no one so beautiful or handsome that she or he never has to empty her or his bowels. (Even the most illustrious person is still human.)
-
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
A kì í fi àyà níní gbọ̀tá.
You do not make enemies unnecessarily just to show boldness.
-
98,548 Abibisika (Black Gold) Points
Ẹ káre, kí ẹ kọ mẹ́ta l’ójoojúmọ́.
-
98,548 Abibisika (Black Gold) Points
Ojo díẹ̀, akin díẹ̀; ìyà ní ń kó jẹni.
A little cowardice [or] a little bravery: all it brings one is trouble. (One should decide whether one will be bold or cowardly; inconsistency in such matters results in suffering.)
-
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
Bí a bá sọkò sọ́jà ará ilé ẹni ló ń bá.
If one throws a stone into the market, it hits one’s neighbor.-
98,548 Abibisika (Black Gold) Points
sọkò tàbí sọ̀kò? -
98,548 Abibisika (Black Gold) Points
Aládùúgbò ẹni ni ọmọ ìyá ẹni.
One’s neighbor is one’s same-mother relative. (A neighbor is as close as any sibling.)
-
- Load More