Group Feed
-
Okunini Ọbádélé Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago
98,618 Abibisika (Black Gold) Points
Ọmọ ẹkùn lajạ́ ń pa.
It is the young of a leopard that a dog kills.
(It is only while one is still vulnerable that one’s enemies can get the better of one.) -
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
A kì í fárí lẹ́yìn olórí.
You cannot shave a man’s head in his absence.
-
98,618 Abibisika (Black Gold) Points
Abínúẹni kò sẹ́ ọ̀ràn deni.
He who wants no good for one does not plead one’s innocence in one’s absence.
(Expect no kindness from an enemy.)
-
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
A kì í dàgbà sí ohun tí a kò bá mọ̀.
One does not get too old for what one does not know.
-
98,618 Abibisika (Black Gold) Points
Wọ́n ní kárúgbó gba ọmọ pọ̀n, ó ní ṣe bí wọ́n mọ̀ pé òun ò léhín; wọ́n ní kó pa ọmọ
jẹ ni?
The old woman is asked to carry a child on her back, and she says but they know she has no teeth; was she asked to eat the child? (Said of people whose comment on a proposition is wildly irrelevant.)
-
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
A ju ara wa lọ, t’ìjàkadi kọ́.
Some are superior to others, it is not a matter of wrestling.
-
98,618 Abibisika (Black Gold) Points
Ààrẹ àgòrò tó bá gbójú, tòun tolúwa rẹ̀ lẹgbẹ́ra.
A subordinate military officer who is audacious is the equal of his superior. (Audaciousness will get one one’s way.)
-
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
Bí a bá ní ká di’jú kí ẹni búburú kọjá, a kò ní mọ ìgbà tí ẹni rere yóò kọjá.
If one decides to close his eyes for the bad person to pass, one will not know when a good person will pass by.
-
98,618 Abibisika (Black Gold) Points
Bí a bá rí èké, à ṣebí èèyàn rere ni; à sọ̀rọ̀ ságbọ̀n a jò.
When one sees a devious person, one mistakes him for a good person; one talks into a basket and it leaks. (It is easy to mistake a bad person for a good one and to place trust in that person.)
-
- Load More