Group Feed
-
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
Adánilóró f’agbára kọ́ ni.
The tormentor only empowers you.-
99,148 Abibisika (Black Gold) Points
Iṣẹ́ ajé le, ó tó ọpa.
Gainful employment is tough, as tough as a supple pole. (Gainful work is not easy.)
-
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
A kì í mú iṣẹ jẹ, ká mú ìṣẹ́ jẹ.
You cannot escape work and escape poverty.-
99,148 Abibisika (Black Gold) Points
Iṣẹ́ -
99,148 Abibisika (Black Gold) Points
Iṣẹ́ l’oògùn ìṣẹ́.
Work is the medicine against poverty.
-
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
A kì í ní’gi lóko,ká má mọ èso rẹ.
You cannot have a tree in your farm without knowing its fruits.-
99,148 Abibisika (Black Gold) Points
rẹ̀. -
99,148 Abibisika (Black Gold) Points
Ìyàn ní ń múni jẹ èso igi-kígi.
It is famine that brings one to eating the fruits of all sorts of trees. (Hard times forceone to unbecoming behavior.)
-
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
A kì í mọ ìwà ilẹ̀ kó kú ni’ṣu.
Once you know the features of a soil, it will not stunt your yam.-
99,148 Abibisika (Black Gold) Points
Ọjọ́ tí àgbẹ̀ ṣíṣe-é bá di kíyèsílẹ̀, ká ṣíwọ̀
oko ríro.
The day farming entails being careful not to hurt the soil, one should stop farming.
(If the basic condition for a trade is interdicted, one should no longer engage in that trade.)
-
- Load More