Group Feed
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
A kì í ṣ’èdá èrò ká yọ̀; bó pẹ́ bó yá oníkálukú yóò relé.
You don’t rejoice in a traveler’s temporary friendship; for he will return home sooner or later.-
99,148 Abibisika (Black Gold) Points
Àjò kì í dùn kónílé má relé.
The journey is never so pleasant that the traveler does not return home. (The traveler should never forget his or her home.)
-
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
Ààrò kì í jó lásán, ọmọ ènìyàn ló ń dá’ná sí i.
The hearth doesn’t burn by itself; it is human beings that put fire in it.-
99,148 Abibisika (Black Gold) Points
Àì-rí èèyàn ní Tẹ́pọ̀nà, wọ́n fi kàríọrán jẹ ìyálóde. On failing to find a human being, Tẹ́pọ̀nà people made a kàríọrán [a person from Iléṣà] their Ìyálóde [the highest female officer in the community]. (Better any human being at all than an Iléṣà person for a high position, but when candidates are scarce, any available person will do.)
-
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
Àáyá bẹ́ sílẹ̀, ó bi sáré.
When the monkey jumps down, it jumps into running.-
99,148 Abibisika (Black Gold) Points
Àáyá bọ́ sílẹ̀, ó bọ́ sílé.
The colobus monkey jumps to the ground; it runs for home. (When danger lurks, the wisest course is to run for safety.)
-
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
Abèèrè ọ̀nà kì í ṣìnà.
He who asks for directions does not miss his way.-
99,148 Abibisika (Black Gold) Points
K’á wí fún ẹni k’á gbọ́; k’á sọ̀rọ̀ fúnni k’á gbà; k’á bèèrè ọ̀nà lọ́wọ́ èrò t’ó kù l’ẹ́hìn k’áyé baà lè yẹni.
If one is spoken to, one should listen; if one is advised, one should heed the advice; one should seek direction from wayfarers who are behind one in order that one’s life might be pleasant. (It is wise to heed advice,…
-
-
Kala Kambon posted an update in the group
Abibitumi Yorùbá Language Resources 4 years ago ·
14,000 Abibisika (Black Gold) Points
Abunnijẹ kì í bunnità.
One who gives you food to feed on will not give you to sell.-
99,148 Abibisika (Black Gold) Points
‘Gbà jẹ’’ ò yẹ àgbà.
‘‘Take this and eat it’’ does not become an elder. (It better becomes an elder to give than to go begging.)
-
- Load More